Ọ̀pọ̀lọpọ̀ atẹjade lórí àwọn ohun ibaraẹnise ìgbàlódé ti sọ pé òjò arọfẹku tàbí òjò omiyale, èyí tó rọ̀ tó kówàhálà bá àwọn ará orílẹ̀-èdè United Arab Emirates (UAE) ṣẹlẹ̀ nítorí pé wọ́n fi kẹ́míkà wá òjò tipátipá.
Àwọn ènìyàn kan ti sọ pé Fídíò kan tí ó ṣe àfihàn àwọn ilé tó ga gan-an ní nǹkan ṣe…
Tí ó bá ń lo àwọn ohun ìgbàlódé ibaraẹnise (social media) ní wákàtí mejidinlaadọta sẹhin, ó ṣeé ṣe kí ó…
Atẹjade kan lórí àwọn ohun ibaraẹnise ìgbàlódé (social media) sọ pé àwọn sójà (soldiers) tí kọlu Okuama, ibì kan ní…
Bello el-Rufai, ọmọ ilé ìgbìmọ̀ asofin tí ó ń sojú Kaduna north federal constituency, sọ pé Hadiza Balarabe ni obìnrin…
William Ruto, Ààrẹ orílẹ̀-èdè Kenya láìpẹ́ sọ pé òhun ni olórí Áfíríkà àkọ́kọ́ láti ogún ọdún sí ìgbà yìí tí…
Our selection of the week's biggest research news and features sent directly to your inbox. Enter your email address, confirm you're happy to receive our emails.
Sign in to your account